Christy Essien-Igbokwe - Seun Rere Lyrics

Omo mi seun rere tie a dara o, Omo mi gbo temi tie a dara o
Omo mi seun rere tie a dara o, Omo mi gbo temi tie a dara o

Iya mi ma seun rere, gbadura fun mi
Baba mi ma seun rere, gbadura fun mi

T'omode ba wuwa buruku won ani iya re loko
T'omode ba wuwa buruku won ani baba re loko

iya mi f'ona to da han mi laye
Baba mi f'iwa to da han mi laye

Aye ti mo wa yi ko ma yemi o
Eyi ni Olorun Keji mi La'aye

iya wa e seun rere, baba wa e seun rere

Instrumentals

iya wa e seun rere, ti wa a dara o
Download this song with Freemake MP3 Boom or Audioham